Lyrics

Barry Jhay & Vstix – Ayeofe Lyrics



Barry Jhay & Vstix – Ayeofe Lyrics
Oya see
Bati wa’aiye pe a ma ri gan la’n ri
Eni ori yo, o di ile
Ile koko ni ti agbe, ile labo simi oko
Kekere na ata tin shey oba fun oju
Eni awi fun oba je ko gbo
Eni a soro fun oba je ko gba
Ma je ki oya a le ti la pa
Eso pe le la aye gba o
Ore mi je ki a se jeje
Ara la mo, a o mo inu

Oju la ri, a i mo inu eni kan
Ti won ba’n ton e
Ore ma tan ara e
Bi ori ba’n yo e
Ore yo ara e
Ko si eni fe ni fun ire, a fi ori eni

Mo ni
Aye o fe o jare
Eni o fe ooo
Aye o fe o
Eni yan o fe
Eniyan o fe ka gbe eru de ori
Ori eni sha lo n ba ni gbe o
Eniyan o fe ka re ru kaso
Ore eni sha
Ore eni sha, lo’n yo ni
Eniyan o fe ka re ru kaso
Ori eni sha
Ori eni sha
Ori eni sha lo yo ni

Ile aye ta wa awa na ja ni
Bo pe bo ya
Ka lu ku a pa da si ile o
Orun sha ni ile
Orun sha ni ile gbogbo wa
Bo pe boya akilolo a pe baba
Bo pe boya agan a pada di olomo
Olorun o le fi wa si le fun iya je
Ojojumo on’ be leyin omo e

Aye o fe o jare
Eni o fe ooo
Aye o fe o
Eni yan o fe
Eniyan o fe ka gbe eru do ori
Ori eni sha lo n ba ni gbe o
Eniyan o fe ka re ru kaso
Ore eni sha
Ore eni sha, lo’n yo ni
Eniyan o fe ka re ru kaso
Ori eni sha
Ori eni sha
Ori eni sha lo yo ni

toBati wa’aiye pe a ma ri gan la’n ri
Eni ori yo, o di ile
Ile koko ni ti agbe, ile labo simi oko
Kekere na ata tin shey oba fun oju
Eni awi fun oba je ko gbo
Eni a soro fun oba je ko gba
Ma je ki oya a le ti la pa

Share On:

TAGS: ,



CLICK HERE TO PROMOTE YOUR MUSIC/VIDEO
Related Posts
 


0 Responses

Leave a Reply